Ẹ Jẹka Jumo F'ọpẹ F'Ọlorun (Single)
by Tolu Akande
Ẹ Jẹ ka jumọ f'ọpẹ f'Ọlọrun
Orin iyin, at'ọpẹ lo yẹ wa
Iyanu n'ifẹ Rẹ si gbogbo wa
Ẹ kọrin 'yin s'Ọba Olore wa
Let us give thanks, together to our God
Songs of praise and thanks we will give
Wonderful in His love unto us all
Sing praises to our benevolent God
Chorus:
Halleluyah! Ogo ni fun Baba
A f'ijo ilu yin Ọlọrun wa
Alaye ni o yin Ọ bo ti yẹ
Halleluyah! Ogo ni fun Baba
Hallelujah! Glory be to our God
We’ll with music and dance praise our Lord
Only the living can worship in truth
Hallelujah! Glory be to our God
Ki l'a fi san j'awọn t'iku ti pa?
Iwọ lo f'ọwọ wọ wa di oni
'Wọ lo n sọ wa to n gba wa lọw'ewu
Ẹ kọrin 'yin s'Olutọju wa
How are we better than those who are dead?
You have showed us kindness even today
You protect us and save us from danger
Sing praises to Him cares for us
Ohun wa ko dun to lati kọrin
Ẹnu wa ko gboro to fun ọpẹ
B'awa n'ẹgbẹrun ahọn nikọkan
Wọn kere ju lati gb'ọla Rẹ ga
Our voices are not sweet enough to sing
Our mouths not able to declare Your true praise
O for a thousand tongues to sing
It wouldn’t be enough
No comments