C.A.C. Hymn 610

Share:

Exo. 15:26

ENGLISH

1. Hear the footsteps of Jesus, He is now passing by,
Bearing balm for the wounded,
healing all who apply;
As He spake to the suff'rer who
lay at the pool.
He is saying this moment "wilt
thou be made whole?"

Wilt thou be made whole,
Wilt thou be made whole,
Oh, come weary sufferer,
Oh, come, sin-sick soul;
See the life-steam is flowing
See the cleansing waves roll;
Step into the current and thou
shalt be whole.

2. ‘Tis the voice of that Saviour
whose merciful call,
Free offers salvation to one and to
He is now beckoning to Him, each sin tainted soul,
And lovingly asking wilt thou be
made whole.

3. Are you halting and struggling, o'er
powered by your sin,
While the waters are troubled, can you not enter in?
Lo, the Saviour stands waiting to
strengthen your soul,
He is earnestly pleading, "Wilt thou be made whole?

4. Blessed Saviour, assist us, to rest on Thy word,
Let the soul healing power, on us
now be outpoured;
Wash away every sin spot, take
perfect control
Say to each trusting spirit, "Wilt thou be made whole?"
Amen.

KulhuD

YORUBA

1. Gbo iro ese Jesu, O nkoja lo bayi,
O ni ‘tura f‘agbogbe, O ns‘awotan arun;
Bo ti so f‘alaisan ni leti adagun,
O nwi be nisisiyi, “O nfe ‘wosan bi?”

O nfe ‘wosan bi?
O nfe ‘wosan bi?
Wa, alailera, wa;
Wa, elese wa;
Wo omi iye ti nsan,
Omi iwenumo,
Wo inu re, iwo yo si ‘wosan


2. Ohun Olugbala ni, ipe anu Re,
Mu igbala ofe wa fun gbogbo eniyan;
O npe gbogbo okan ti eru ese npa,
O nfi ife bere pe: “O nfe ‘wosan bi?”

3. Ara nni o, eru ese nwo o l‘ORUN,
O ko ha le wonu omi ni bi o ti nru?
Wo Oluwa nduro lati fun o l‘okun,
O si nfi ‘fe bere pe: “O nfe ‘wosan bi?”

4. Ran wa lowo Jesu ka gbeke l‘oro Re,
Je ki emi iwosan be le wa loni yi,
We abawon ese nu, si s‘akoso wa,
So f‘okan to nwa o pe: “O nfe ‘wosan bi?”

1 comment: