C.A.C. Hymn 400

Share:

Ps. 57:7

ENGLISH

1. Once more, my soul, thy Saviour,
Thro' the Word Is offer'd full and free;
And now, O Lord, I must, I must
decide:
Shall I accept of Thee?

I will! I will!
I will, God helping me,
I will O Lord be thine
Thy precious blood was shed
to purchase me
I will be wholly Thine!

2. mf By grace I will Thy mercy now receive,
Thy love my heart hath won;
On Thee, O Christ, I will, I will
believe,
And trust in Thee alone!

3. Thou knowest, Lord, how very weak I am
And how I fear to stray;
For strength to serve I look to Thee alone
The strength Thou must supply!

4. And now, O Lord, give all with us today
The grace to join our song;
And from the heart to gladly with us say;
"I will to Christ belong!"

5. To all who came, when Thou wast here below
And said, "O Lord, wilt Thou?"
To them, "I will!" was ever Thy
reply:
We rest upon it now.
Amen.

KulhuD

YORUBA

1. Okan mi, a tun fi Jesu lo o
L‘ekan si n‘nu oro Re,
Nisisiyi, Oluwa, un o pinnu
Nki o ha gba Tire?

Mo fe, mo fe
B‘Olorun se ‘ranwo
Emi fe je tire
Eje Re ‘yebiye lo fi ra mi,
Emi yo je Tire

2. Nipa or‘-ofe l‘em‘o r‘anu gba,
Mo jere ife Re.
Kristi IWO li emi o gbagbo,
Uno si gbekele O.

3. Oluwa, IWO MO ailera mi
Bi nko ti fe sako,
‘WO nikan lo le fun mi l‘agbara
Lati josin fun O.

4. Oluwa f’or‘ofe fun wa loni
Ka le jumo'korin:
Ki gbogbo wa SO tokantokan pe,
Emiyo je ti Krist‘.

5. Awon to t‘o O wa nigba aye Re
Lati toro ‘bukun,
“Mo fe? ni idahun ti won ri gba:
On na la gbokan le.
Amin.

2 comments:

  1. Thanks for posting the hymn,much-loved

    ReplyDelete
  2. Pls what is the title of the Yoruba version of this Hymn?

    ReplyDelete